• Home
  • Advertise With Us
  • Cookies Policy
  • DMCA Policy
  • EULA
  • Privacy Policy
No Result
View All Result
  • Home
  • Advertise With Us
  • Cookies Policy
  • DMCA Policy
  • EULA
  • Privacy Policy
No Result
View All Result
Apple Lyrics
No Result
View All Result

Tope Alabi – Loro Lero Ati Ni’se Lyrics

Tope Alabi Hymnal (Volume 1)
Tope Alabi – Hymnal (Volume 1)

Tope Alabi Loro Lero Ati Ni’se Lyrics

[Verse 1]
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

[Chrous]
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

[Verse 2]
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

[Verse 3]
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise

[Chrous]
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

Written by; Tope Alabi
Released date; 9 November, 2020

https://www.applelyrics.com/watch?v=eAUus3xZLLg

Loro Lero Ati Ni’se Lyrics by Tope Alabi

    Lyrics Information & Credits

  • Song Title:
  • Artist:
  • Written by:
  • Genre:
  • Album:
  • Release Date:

You May Also Like

Tim Godfrey Iyanu a Sele Lyrics

Tim Godfrey – Iyanu a Sele Lyrics ft. Pastor E.A Adeboye, Tope Alabi

Tope-Alabi-Hymnal-Volume-1-3-1

Tope Alabi – Aso Mi A Funfun Lau Lyrics

Tope-Alabi-Hymnal-Volume-1-3-1

Tope Alabi – Ba Eleda Laja Lyrics

Tope Alabi – Jesu Ore Otito Lyrics

Tope Alabi – Oluwa, Anu Re Duro Lyrics

Tope Alabi – Eyin Oluwa, Halleluyah Lyrics

Tope Alabi – Kosi’bi Ti’mole Re Kode Lyrics

Tope Alabi – Lae La O Ma Bo Oluwa Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

  • Home
  • Hot Lyrics
  • DMCA Policy
  • Advertise Here
  • Cookies Policy

© 2022 - AppleLyrics.com - All rights reserved to respective artists.

No Result
View All Result
  • Home
  • Advertise With Us
  • Cookies Policy
  • DMCA Policy
  • EULA
  • Privacy Policy

© 2022 - AppleLyrics.com - All rights reserved to respective artists.